1. Ha! egbe mi e w‘asia Bi ti nfe lele! Ogun Jesu fere de na, A fere segun.
“D‘odi mu, Emi fere de”Beni Jesu nwi, Ran ‘dahun pada s‘orun, pe “Awa o di mu.”
2. Wo opo ogun ti mbo wa; Esu nko won bo; Awon alagba…
Home
Feed
Search
Library
Download